Ìṣẹ́gun l'órí IkúÀpẹrẹ
Gbàdúrà: Ọlọ́run, bà mi pàdé níbí, bí mo ti ń wá Ọ nínú Ọ̀rọ̀ Rẹ. Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú àfojúsùn àti ìṣípá làti rí ohun tí Ọlọ́run ní l'étò fún ọ.
Ka: àṣàyàn ẹsẹ Ìwé-mímọ́ ní ṣísẹ̀ǹtèlé. Ṣe àkíyèsí àwọn ọ̀rọ̀ àti gbólóhùn tó kàsíàrà kí ọ sì tún wọn kà lẹ́ẹ̀kan sii.
Ronú: lórí ohun tí o kọ sí ọ bí ọ ṣe ń kàá. Ronú nípa ohun tí Ọlọ́run ń bá ọ sọ ní ìkóríta ayé rẹ yìí.
Fèsì: sí àyọkà yí. Bá Ọlọ́run sọ̀rọ̀ tààrà l'órí ohun tí ó wà l'ọ́kàn àti ẹ̀mí rẹ. Wá ọ̀nà láti gbé ìgbé-ayé ohun tí o ṣ'àwárí.
Ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn òǹkàwé wa ló ní ìtàn àràmàǹdà nípa ìbáṣepọ̀ wọn pẹ̀lú Bíbélì. A pè ọ́ kí o kànsí ìkànnì tó wà n'ísàlẹ̀ yìí, kí a baà le mọ́ ọ́ síi àti àwọn òǹkàwé míràn bíi tìrẹ. Ìdarapọ̀ rẹ yíó ran Ẹgbẹ́ Bíbélì Améríkà lọ́wọ́ láti tẹ̀síwájú láti máa pèsè àwọn ohun èlò Bíbélì tó yanrantí fún àwọn ènìyàn n'íbi gbogbo, yíó sì ṣe àfikún ìdàgbàsókè ohun èlò Bíbélì titun.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Wọ́n ti máa ń sọ fún wa pé, "Bẹ́ẹ́ ní ayé rí," àmọ́ àwọn àṣamọ̀ báyìí kìí dín ìrora tó wà nínú pípa àdánù ẹni tí a fẹ́ràn kù. Kọ́ láti sá tọ Ọlọ́run lọ nígbàtí o bá ń d'ojúkọ àwọn ìpèníjà ayé tó le jù.
More