Ìṣẹ́gun l'órí Ikú

Ọjọ́ 7
Wọ́n ti máa ń sọ fún wa pé, "Bẹ́ẹ́ ní ayé rí," àmọ́ àwọn àṣamọ̀ báyìí kìí dín ìrora tó wà nínú pípa àdánù ẹni tí a fẹ́ràn kù. Kọ́ láti sá tọ Ọlọ́run lọ nígbàtí o bá ń d'ojúkọ àwọn ìpèníjà ayé tó le jù.
A dúpẹ́ lọ́wọ́ Ẹgbẹ́ Bíbélì Améríkà fún àkóyawọ́ wọn nípa pípèsè ètò ẹ̀kọ́ Ṣíṣàwárí Ọ̀rọ̀ Náà. Láti mọ̀ síi nípa ètò ẹ̀kọ́ Ṣíṣàwárí Ọ̀rọ̀ Náà, kàn sí: www.AmericanBible.org
Nípa Akéde