Jẹ́ kí a ka Bíbélì papọ̀ (December)Àpẹrẹ

Let's Read the Bible Together (December)

Ọjọ́ 28 nínú 31

Ọjọ́ 27Ọjọ́ 29

Nípa Ìpèsè yìí

Let's Read the Bible Together (December)

Apá Kejìlá a ti onipin mejila, ètò yìí wà láti darí àwọn egbé tàbí ọrẹ nínú gbogbo Bíbélì lápapọ̀ ní ọjọ́ 365. Pe àwọn mìíràn láti darapọ̀ mọ́ ọ ní gbogbo ìgbà tí o bá bèrè apá titun ní osoosu. Ìpín yìí le bá Bíbélì Olohun ṣiṣẹ - tẹtisilẹ ní bíi ogun iṣẹju lójoojúmó! Apá kọọkan wá pẹ̀lú orí Bíbélì láti inú Májẹ̀mú àtijọ́ àti Majẹmu titun, pẹ̀lú Ìwé Orin Dáfídì láàrin wọn. Apá Kejìlá ní àwọn Iwé Aisaya, Mika, Pétérù Kínní, Pétérù Kejì, Jòhánù Kínní, Jòhánù Kejì, Jòhánù Kẹta, àti Juda.

More

A fẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ Life.Church fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ sí, jọwọ lọ sí: www.lifechurch.tv