Alábùkún fún ni OLúWA! Nítorí pé ó ti gbọ́ ohùn ẹ̀bẹ̀ mi. OLúWA ni agbára mi àti asà mi; nínú rẹ̀ ni mo gbẹ́kẹ̀lé; àní, ó sì ràn mí lọ́wọ́. Ọkàn mi sì gbé sókè fún ayọ̀ àní pẹ̀lú orin mi mo fi ọpẹ́ fún un. OLúWA ni agbára àwọn ènìyàn rẹ̀ òun ni odi ìgbàlà àwọn ẹni ààmì òróró rẹ̀. Ìwọ gba àwọn ènìyàn rẹ là, kí o sì bùkún àwọn ajogún rẹ; di olùṣọ́-àgùntàn wọn, kí o sì gbé wọn lékè títí ayérayé.
Kà Saamu 28
Feti si Saamu 28
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Saamu 28:6-9
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò