Ẹ gbé orí yín sókè, háà! Ẹ̀yin ọ̀nà; Kí á sì gbe yín sókè, ẹyin ìlẹ̀kùn ayérayé! Kí ọba ògo le è wọlé. Ta ni ọba ògo náà? OLúWA tí ó lágbára tí ó sì le, OLúWA gan an, tí ó lágbára ní ogun. Gbé orí yín sókè, ẹyin ọ̀nà; kí a sì gbé e yín sókè, ẹ̀yin ìlẹ̀kùn ayérayé, kí Ọba ògo le è wọlé wá. Ta ni Ọba ògo náà? OLúWA àwọn ọmọ-ogun Òun ni Ọba ògo náà. Sela.
Kà Saamu 24
Feti si Saamu 24
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Saamu 24:7-10
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò