Òwe 8:18-20

Òwe 8:18-20 YCB

Lọ́dọ̀ mi ni ọrọ̀ àti ọlá wà ọrọ̀ tí í tọ́jọ́ àti ìgbéga rere. Èso mi dára ju wúrà dáradára lọ; ohun tí mò ń mú wá ju àṣàyàn fàdákà lọ. Mò ń rìn ní ọ̀nà òdodo, ní ojú ọ̀nà òtítọ́