Owe 8:18-20
Owe 8:18-20 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọrọ̀ ati ọlá mbẹ lọwọ mi, ani ọrọ̀ daradara ati ododo. Ere mi ta wura yọ; nitõtọ, jù wura daradara lọ: ati ọrọ̀ mi jù fadaka àṣayan lọ. Emi nrìn li ọ̀na ododo, larin ipa-ọ̀na idajọ
Pín
Kà Owe 8Ọrọ̀ ati ọlá mbẹ lọwọ mi, ani ọrọ̀ daradara ati ododo. Ere mi ta wura yọ; nitõtọ, jù wura daradara lọ: ati ọrọ̀ mi jù fadaka àṣayan lọ. Emi nrìn li ọ̀na ododo, larin ipa-ọ̀na idajọ