Òwe 19:22-23

Òwe 19:22-23 YCB

Ohun tí ènìyàn ń fẹ́ ni ìfẹ́ tí kì í yẹ̀; ó sàn láti jẹ́ tálákà ju òpùrọ́ lọ. Ìbẹ̀rù OLúWA ń mú ìyè wá: nígbà náà ọkàn ń balẹ̀, láìsí ewu.