ÌWÉ ÒWE 19:22-23

ÌWÉ ÒWE 19:22-23 YCE

Ohun tí ayé ń fẹ́ lára eniyan ni òtítọ́ inú, talaka sì sàn ju òpùrọ́ lọ. Ìbẹ̀rù OLUWA a máa mú ìyè wá, ẹni tí ó ní i yóo ní ìfọ̀kànbalẹ̀, ìṣẹ̀lẹ̀ burúkú kan kò ní ṣẹlẹ̀ sí i.