Owe 19:22-23
Owe 19:22-23 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹwà enia ni iṣeun rẹ̀: talaka enia si san jù eleke lọ. Ibẹ̀ru Oluwa tẹ̀ si ìye: ẹniti o ni i yio joko ni itẹlọrun; a kì yio fi ibi bẹ̀ ẹ wọ́.
Pín
Kà Owe 19Ẹwà enia ni iṣeun rẹ̀: talaka enia si san jù eleke lọ. Ibẹ̀ru Oluwa tẹ̀ si ìye: ẹniti o ni i yio joko ni itẹlọrun; a kì yio fi ibi bẹ̀ ẹ wọ́.