Owe 19:22-23

Owe 19:22-23 YBCV

Ẹwà enia ni iṣeun rẹ̀: talaka enia si san jù eleke lọ. Ibẹ̀ru Oluwa tẹ̀ si ìye: ẹniti o ni i yio joko ni itẹlọrun; a kì yio fi ibi bẹ̀ ẹ wọ́.