Òwe 18:23-24

Òwe 18:23-24 YCB

Tálákà ń bẹ̀bẹ̀ fún àánú, ṣùgbọ́n ọlọ́rọ̀ a dáhùn pẹ̀lú ìkanra. Ènìyàn tí ó ní ọ̀rẹ́ púpọ̀ le è parun ṣùgbọ́n ọ̀rẹ́ kan wà tí ó súnmọ́ ni tímọ́tímọ́ ju arákùnrin.