Owe 18:23-24
Owe 18:23-24 Bibeli Mimọ (YBCV)
Talaka a ma bẹ̀ ẹ̀bẹ; ṣugbọn ọlọrọ̀ a ma fi ikanra dahùn. Ẹniti o ni ọrẹ́ pupọ, o ṣe e si iparun ara rẹ̀; ọrẹ́ kan si mbẹ ti o fi ara mọni ju arakunrin lọ.
Pín
Kà Owe 18Owe 18:23-24 Bibeli Mimọ (YBCV)
Talaka a ma bẹ̀ ẹ̀bẹ; ṣugbọn ọlọrọ̀ a ma fi ikanra dahùn. Ẹniti o ni ọrẹ́ pupọ, o ṣe e si iparun ara rẹ̀; ọrẹ́ kan si mbẹ ti o fi ara mọni ju arakunrin lọ.
Pín
Kà Owe 18Owe 18:23-24 Yoruba Bible (YCE)
Ẹ̀bẹ̀ ni talaka bẹ̀, ṣugbọn ọlọ́rọ̀ á dáhùn tìkanra-tìkanra. Àwọn ọ̀rẹ́ kan wà, ọ̀rẹ́ àfẹnujẹ́ ni wọ́n, ṣugbọn ọ̀rẹ́ mìíràn wà tí ó fi ara mọ́ni ju ọmọ ìyá ẹni lọ.
Pín
Kà Owe 18