ÌWÉ ÒWE 18:23-24

ÌWÉ ÒWE 18:23-24 YCE

Ẹ̀bẹ̀ ni talaka bẹ̀, ṣugbọn ọlọ́rọ̀ á dáhùn tìkanra-tìkanra. Àwọn ọ̀rẹ́ kan wà, ọ̀rẹ́ àfẹnujẹ́ ni wọ́n, ṣugbọn ọ̀rẹ́ mìíràn wà tí ó fi ara mọ́ni ju ọmọ ìyá ẹni lọ.