Òwe 13:5-6

Òwe 13:5-6 YCB

Olódodo kórìíra ohun tí í ṣe irọ́ Ṣùgbọ́n ènìyàn búburú hu ìwà ìríra àti ìtìjú. Òdodo ń ṣamọ̀nà ènìyàn olóòtítọ́ inú, ṣùgbọ́n ìwà búburú ṣí ẹlẹ́ṣẹ̀ ní ipò.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Òwe 13:5-6

Òwe 13:5-6 - Olódodo kórìíra ohun tí í ṣe irọ́
Ṣùgbọ́n ènìyàn búburú hu ìwà ìríra àti ìtìjú.

Òdodo ń ṣamọ̀nà ènìyàn olóòtítọ́ inú,
ṣùgbọ́n ìwà búburú ṣí ẹlẹ́ṣẹ̀ ní ipò.Òwe 13:5-6 - Olódodo kórìíra ohun tí í ṣe irọ́
Ṣùgbọ́n ènìyàn búburú hu ìwà ìríra àti ìtìjú.

Òdodo ń ṣamọ̀nà ènìyàn olóòtítọ́ inú,
ṣùgbọ́n ìwà búburú ṣí ẹlẹ́ṣẹ̀ ní ipò.