Owe 13:5-6

Owe 13:5-6 YBCV

Olododo korira ẹ̀tan; ṣugbọn enia buburu mu ni hu ìwa irira on itiju. Ododo pa aduro-ṣinṣin li ọ̀na mọ́; ṣugbọn ìwa-buburu ni imuni ṣubu sinu ẹ̀ṣẹ.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Owe 13:5-6

Owe 13:5-6 - Olododo korira ẹ̀tan; ṣugbọn enia buburu mu ni hu ìwa irira on itiju.
Ododo pa aduro-ṣinṣin li ọ̀na mọ́; ṣugbọn ìwa-buburu ni imuni ṣubu sinu ẹ̀ṣẹ.Owe 13:5-6 - Olododo korira ẹ̀tan; ṣugbọn enia buburu mu ni hu ìwa irira on itiju.
Ododo pa aduro-ṣinṣin li ọ̀na mọ́; ṣugbọn ìwa-buburu ni imuni ṣubu sinu ẹ̀ṣẹ.