Owe 13:5-6
Owe 13:5-6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Olódodo kórìíra ohun tí í ṣe irọ́ Ṣùgbọ́n ènìyàn búburú hu ìwà ìríra àti ìtìjú. Òdodo ń ṣamọ̀nà ènìyàn olóòtítọ́ inú, ṣùgbọ́n ìwà búburú ṣí ẹlẹ́ṣẹ̀ ní ipò.
Pín
Kà Owe 13Owe 13:5-6 Bibeli Mimọ (YBCV)
Olododo korira ẹ̀tan; ṣugbọn enia buburu mu ni hu ìwa irira on itiju. Ododo pa aduro-ṣinṣin li ọ̀na mọ́; ṣugbọn ìwa-buburu ni imuni ṣubu sinu ẹ̀ṣẹ.
Pín
Kà Owe 13