O. Daf 86:5-7

O. Daf 86:5-7 YBCV

Nitori iwọ, Oluwa, o ṣeun, o si mura ati dariji; o si pọ̀ li ãnu fun gbogbo awọn ti nkepè ọ. Oluwa, fi eti si adura mi; ki o si fiye si ohùn ẹ̀bẹ mi. Li ọjọ ipọnju mi, emi o kepè ọ: nitori ti iwọ o da mi lohùn.