O. Daf 147:4-6

O. Daf 147:4-6 YBCV

O ka iye awọn ìrawọ; o si sọ gbogbo wọn li orukọ. Oluwa wa tobi, ati alagbara nla: oye rẹ̀ kò li opin. Oluwa gbé awọn onirẹlẹ soke: o rẹ̀ awọn enia buburu si ilẹyilẹ.