Òun ló mọ iye àwọn ìràwọ̀, òun ló sì fún gbogbo wọn lórúkọ. OLUWA wa tóbi, ó sì lágbára pupọ òye rẹ̀ kò ní ìwọ̀n. OLUWA ní ń gbé àwọn onírẹ̀lẹ̀ ró, òun ni ó sì ń sọ àwọn eniyan burúkú di ilẹ̀ẹ́lẹ̀.
Kà ORIN DAFIDI 147
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ORIN DAFIDI 147:4-6
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò