O. Daf 147:4-6
O. Daf 147:4-6 Yoruba Bible (YCE)
Òun ló mọ iye àwọn ìràwọ̀, òun ló sì fún gbogbo wọn lórúkọ. OLUWA wa tóbi, ó sì lágbára pupọ òye rẹ̀ kò ní ìwọ̀n. OLUWA ní ń gbé àwọn onírẹ̀lẹ̀ ró, òun ni ó sì ń sọ àwọn eniyan burúkú di ilẹ̀ẹ́lẹ̀.