O. Daf 118:15-17

O. Daf 118:15-17 YBCV

Ìró ayọ̀ ati ti ìṣẹ́gun mbẹ ninu agọ awọn olododo; ọwọ ọtún Oluwa li a gbega: ọwọ ọtún Oluwa nṣe agbara. Ọwọ ọtún Oluwa li a gbega: ọwọ ọtún Oluwa nṣe agbara. Emi kì yio kú, bikoṣe yiyè, ki emi ki o si ma rohin iṣẹ Oluwa.