ORIN DAFIDI 118:15-17

ORIN DAFIDI 118:15-17 YCE

Ẹ gbọ́ orin ayọ̀ ìṣẹ́gun, ninu àgọ́ àwọn olódodo. “Ọwọ́ ọ̀tún OLUWA ti ṣe iṣẹ́ agbára ńlá. A gbé ọwọ́ ọ̀tún OLUWA ga, ọwọ́ ọ̀tún OLUWA ti ṣe iṣẹ́ agbára ńlá!” N ò ní kú, yíyè ni n óo yè, n óo sì máa fọnrere nǹkan tí OLUWA ṣe.