Owe 31:16-18

Owe 31:16-18 YBCV

O kiyesi oko, o si mu u: ère ọwọ rẹ̀ li o fi gbin ọgbà-ajara. O fi agbara gbá ẹ̀gbẹ rẹ̀ li ọjá, o si mu apa rẹ̀ mejeji le. O kiyesi i pe ọjà on dara: fitila rẹ̀ kò kú li oru.