Bí ó bá rí ilẹ̀ oko, a yẹ̀ ẹ́ wò, a sì rà á, a sì fi èrè iṣẹ́ rẹ̀ gbin ọgbà àjàrà. A fi agbára fún ọ̀já mọ́nú, a sì tẹpá mọ́ṣẹ́. A máa mójútó ọjà tí ó ń tà, fìtílà rẹ̀ kì í sì í kú lóru.
Kà ÌWÉ ÒWE 31
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ÌWÉ ÒWE 31:16-18
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò