Owe 3:7-8

Owe 3:7-8 YBCV

Máṣe ọlọgbọ́n li oju ara rẹ; bẹ̀ru Oluwa, ki o si kuro ninu ibi. On o ṣe ilera si idodo rẹ, ati itura si egungun rẹ.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Owe 3:7-8

Owe 3:7-8 - Máṣe ọlọgbọ́n li oju ara rẹ; bẹ̀ru Oluwa, ki o si kuro ninu ibi.
On o ṣe ilera si idodo rẹ, ati itura si egungun rẹ.Owe 3:7-8 - Máṣe ọlọgbọ́n li oju ara rẹ; bẹ̀ru Oluwa, ki o si kuro ninu ibi.
On o ṣe ilera si idodo rẹ, ati itura si egungun rẹ.