Owe 14:30-31

Owe 14:30-31 YBCV

Ọkàn ti o yè kõro ni ìye ara; ṣugbọn ilara ni ibajẹ egungun. Ẹniti o ba nni talaka lara, o gàn Ẹlẹda rẹ̀; ṣugbọn ẹniti o ṣãnu fun talaka o bu ọlá fun u.