Owe 14:30-31
Owe 14:30-31 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọkàn ti o yè kõro ni ìye ara; ṣugbọn ilara ni ibajẹ egungun. Ẹniti o ba nni talaka lara, o gàn Ẹlẹda rẹ̀; ṣugbọn ẹniti o ṣãnu fun talaka o bu ọlá fun u.
Pín
Kà Owe 14Ọkàn ti o yè kõro ni ìye ara; ṣugbọn ilara ni ibajẹ egungun. Ẹniti o ba nni talaka lara, o gàn Ẹlẹda rẹ̀; ṣugbọn ẹniti o ṣãnu fun talaka o bu ọlá fun u.