ÌWÉ ÒWE 14:30-31

ÌWÉ ÒWE 14:30-31 YCE

Ìbàlẹ̀ ọkàn a máa mú kí ara dá ṣáṣá, ṣugbọn ìlara a máa dá egbò sinu eegun. Ẹni tí ó bá ni talaka lára àbùkù Ẹlẹ́dàá rẹ̀ ni ó ń ta, ṣugbọn ẹni tí ó ṣàánú fún àwọn aláìní ń bu ọlá fún Ẹlẹ́dàá rẹ̀.