ORIN DAFIDI 94:12-14

ORIN DAFIDI 94:12-14 YCE

Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí o bá báwí, OLUWA, tí o sì kọ́ ní òfin rẹ, kí ó lè sinmi lọ́wọ́ ọjọ́ ìṣòro, títí tí a ó fi gbẹ́ kòtò fún eniyan burúkú. Nítorí OLUWA kò ní kọ àwọn eniyan rẹ̀ sílẹ̀; kò ní ṣá àwọn eniyan ìní rẹ̀ tì