Saamu 94:12-14

Saamu 94:12-14 YCB

Ìbùkún ni fún ènìyàn náà tí ìwọ bá wí, OLúWA, ẹni tí ìwọ kọ́ nínú òfin rẹ; Ìwọ gbà á kúrò nínú ọjọ́ ibi, títí a ó fi wa ihò sílẹ̀ fún ẹni búburú. Nítorí OLúWA kò ní kọ àwọn ènìyàn rẹ̀ sílẹ̀; Òun kò sì ní kọ ilẹ̀ ìní rẹ̀ sílẹ̀.