ORIN DAFIDI 68:1

ORIN DAFIDI 68:1 YCE

Kí Ọlọrun dìde, kí àwọn ọ̀tá rẹ tú ká. Kí àwọn tí ó kórìíra rẹ̀ sá níwájú rẹ̀.