KI Ọlọrun ki o dide, ki a si tú awọn ọta rẹ̀ ka: ki awọn ti o korira rẹ̀ pẹlu, ki nwọn ki o salọ kuro niwaju rẹ̀.
Kí Ọlọrun dìde, kí àwọn ọ̀tá rẹ tú ká. Kí àwọn tí ó kórìíra rẹ̀ sá níwájú rẹ̀.
Kí Ọlọ́run kí ó dìde, kí àwọn ọ̀tá rẹ̀ kí ó fọ́nká; kí àwọn ọ̀tá rẹ̀ kí ó sá níwájú rẹ̀.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò