O sá mọ gbogbo ìdààmú mi; ati bí omijé mi ti pọ̀ tó, wọ́n ṣá wà ní àkọsílẹ̀ ninu ìwé rẹ. A óo lé àwọn ọ̀tá mi pada ní ọjọ́ tí mo bá ké pè ọ́. Mo mọ̀ dájú pé Ọlọrun ń bẹ fún mi. Ọlọrun, tí mo yin ọ̀rọ̀ rẹ̀, OLUWA, tí mo yin ọ̀rọ̀ rẹ̀; Ọlọrun ni mo gbẹ́kẹ̀lé láìbẹ̀rù. Kí ni eniyan ẹlẹ́ran ara lè fi mí ṣe?
Kà ORIN DAFIDI 56
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ORIN DAFIDI 56:8-11
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò