Ìwọ ni mo gbé ojú sókè sí, ìwọ tí o gúnwà ní ọ̀run. Wò ó, bí iranṣẹkunrin ti máa ń wo ojú oluwa rẹ̀, tí iranṣẹbinrin sì máa ń wo ojú oluwa rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni à ń wo ojú OLUWA, Ọlọrun wa, títí tí yóo fi ṣàánú wa. Ṣàánú wa, OLUWA, ṣàánú wa, ẹ̀gàn yìí ti pọ̀ jù! Ẹ̀gàn àwọn onírera ti pọ̀ jù fún wa; yẹ̀yẹ́ àwọn onigbeeraga sì ti sú wa.
Kà ORIN DAFIDI 123
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ORIN DAFIDI 123:1-4
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò