ORIN DAFIDI 118:23-24

ORIN DAFIDI 118:23-24 YCE

OLUWA ló ṣe èyí; ó sì jẹ́ ohun ìyanu lójú wa. Òní ni ọjọ́ tí OLUWA dá, ẹ jẹ́ kí á máa yọ̀, kí inú wa sì máa dùn.