Saamu 118:23-24

Saamu 118:23-24 YCB

OLúWA ti ṣe èyí, ó ṣe ìyanu ní ojú wa. Èyí ni ọjọ́ tí OLúWA dá: ẹ jẹ́ kí ayọ̀ kí inú wa sì máa dùn nínú rẹ̀.