O. Daf 118:23-24
O. Daf 118:23-24 Bibeli Mimọ (YBCV)
Lati ọdọ Oluwa li eyi: o ṣe iyanu li oju wa. Eyi li ọjọ ti Oluwa da: awa o ma yọ̀, inu wa yio si ma dùn ninu rẹ̀.
O. Daf 118:23-24 Yoruba Bible (YCE)
OLUWA ló ṣe èyí; ó sì jẹ́ ohun ìyanu lójú wa. Òní ni ọjọ́ tí OLUWA dá, ẹ jẹ́ kí á máa yọ̀, kí inú wa sì máa dùn.