ÌdánilójúÀpẹrẹ
Olórun fé kí o Mọ̀ wípé a tí gbà ọ́ là àti pé ìwọ yóò lọ sí òrun! Ìdánilójú rẹ n dàgbà nípasè ìbápàdé pẹ̀lú Olórun àti ṣíṣe àsàrò nínú Ọ̀rọ̀ọ Rẹ̀. Nígbà tí o bá há, àwọn ẹsẹ̀ Bíbélì tó tẹ̀lé sórí, yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti fi gbogbo ìgbẹ́kẹ̀lé rẹ sínú Ọlọ́run, fún gbogbo ọjọ́ ayé rẹ. Jẹ́kí ayé rẹ ní ìyípadà nípasẹ̀ kíkọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run pẹ̀lú àkọ́sórí! Fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìlànà fún híhá Ìwé Mímó sórí, sábẹwò MemLok.com Fún Àwọn Ètò MemLok míràn
Nípa Ìpèsè yìí
Olórun fé jé kí o mò pé a tí gbà onlà àti pé ìwo yóò lọ sí òrun! Ìdánilójú rè ń dàgbà sí nípasẹ ìbápàdé pẹ̀lú Olórun àti ṣíṣe àsàrò nínú Ọ̀rọ̀ Rẹ̀. Àwọn ẹsẹ̀ tó tẹ̀lé, nígbà tí o bá há wọn sórí, lè ràn ọ́ lọ́wọ́ láti simi ni ìdánilójú nínú Ọlọ́run ní gbogbo ọjọ́ ayé rè. Jé kí ayé rẹ ní ìyípadà nípa híhá Àwọn Ìwé Mímó sórí! Fún ìlànà ekún rẹ́rẹ́ fún híhá Àwọn Ìwé Mímó sórí, lọ si MemLok.com
More