Ìjìyà
![Ìjìyà](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F80%2F1280x720.jpg&w=3840&q=75)
Ọjọ́ 4
Ìjìyà jẹ́ ọ̀kan lára ìpìlẹ̀ ìgbàgbọ́ Kristiẹni - 2 Timoti 3:12. Ìdáhùn rere rẹ sí-i máa dàgbà nípasẹ pípàdé Ọlọ́run àti ṣíṣàrò nínú Ọ̀rọ Rẹ̀. Àwọn ẹsẹ̀ tí ó tẹ̀lé-e, nígbà tí a bá há wọn sórí, lè fún ọ ní ìṣírí sí ìdáhùn Ọlọ́run sì ìjìyà.
A fẹ́ dúpẹ́ l'ọ́wọ MemLok, Ètò Ìrántí Bíbélì, fún ìpèsè ìlànà ètò yìí. Fún àlàyé síi nípa MemLok, lọ sí: http://www.MemLok.com
Nípa Akéde