GalatiaÀpẹrẹ

Galatia

Ọjọ́ 1 nínú 6

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 2

Nípa Ìpèsè yìí

Galatia

Bí o bá ńní àníyàn pé o kò gbé ìgbésẹ̀ tó tó láti jèèrè ìgbàlà rẹ, ètò ẹsẹ̀-Bibeli-kan-lójúmọ́ yìí jálẹ̀ ìwé Galatia yóò rán ọ létí: Jesu ti ṣe ohun gbogbo parí! Ẹbọ Rẹ̀ ti tú ọ sílẹ̀ lọ́wọ́ pípa-òfin-mọ́. A gbà ọ́ là nípasẹ̀ ore-ọ̀fẹ́ Rẹ̀, Ẹ̀mí-mímọ́ Rẹ̀ sì ti fún ọ lágbára láti gbé ìgbé-ayé tó wù Ú. YouVersion ni ó ṣàgbékalẹ̀ ètò yìí.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Mount Zion Faith Ministry fún pípèsè ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí i, jọ̀wọ́ lọ sí: https://mountzionfilm.org/