Oluwa, ninu awọn oriṣa kò si ọ̀kan ti o dabi rẹ, bẹ̃ni kò si iṣẹ kan ti o dabi iṣẹ rẹ.
OLUWA, kò sí èyí tí ó dàbí rẹ ninu àwọn oriṣa; kò sì sí iṣẹ́ ẹni tí ó dàbí iṣẹ́ rẹ.
Nínú àwọn òrìṣà kò sí ẹni tí ó dàbí i rẹ, OLúWA: kò sí àwọn iṣẹ́ tí a lè fiwé tìrẹ.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò