O. Daf 33:4-5
O. Daf 33:4-5 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori ti ọ̀rọ Oluwa tọ́: ati gbogbo iṣẹ rẹ̀ li a nṣe ninu otitọ. O fẹ otitọ ati idajọ: ilẹ aiye kún fun ãnu Oluwa.
Pín
Kà O. Daf 33Nitori ti ọ̀rọ Oluwa tọ́: ati gbogbo iṣẹ rẹ̀ li a nṣe ninu otitọ. O fẹ otitọ ati idajọ: ilẹ aiye kún fun ãnu Oluwa.