Saamu 33:4-5
Saamu 33:4-5 YCB
Nítorí pé ọ̀rọ̀ OLúWA dúró ṣinṣin, gbogbo iṣẹ́ rẹ̀ ni à ń ṣe nínú òtítọ́. Ó fẹ́ òtítọ́ àti ìdájọ́; ilé ayé kún fún ìdúró ṣinṣin àti àánú OLúWA.