Owe 8:34
Owe 8:34 Yoruba Bible (YCE)
Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí ó bá gbọ́ tèmi, tí ó ń ṣọ́nà lojoojumọ ní ẹnu ọ̀nà àgbàlá mi, tí ó dúró sí ẹnu ọ̀nà ilé mi.
Pín
Kà Owe 8Owe 8:34 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ibukún ni fun ẹniti o gbọ́ temi, ti o nṣọ́ ẹnu-ọ̀na mi lojojumọ, ti o si nduro ti opó ẹnu-ilẹkun mi.
Pín
Kà Owe 8