Owe 21:8-9
Owe 21:8-9 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹnikẹni ti o nrìn ọ̀na ayidayida, enia buburu ni; ṣugbọn oninu funfun ni iṣẹ rẹ̀ tọ́. O san lati joko ni igun òke àja, jù pẹlu onija obinrin lọ ninu ile ajumọgbe.
Pín
Kà Owe 21Ẹnikẹni ti o nrìn ọ̀na ayidayida, enia buburu ni; ṣugbọn oninu funfun ni iṣẹ rẹ̀ tọ́. O san lati joko ni igun òke àja, jù pẹlu onija obinrin lọ ninu ile ajumọgbe.