Ọ̀nà ẹlẹ́bi kì í gún, ṣugbọn ìrìn aláìlẹ́bi a máa tọ́. Ó sàn láti máa gbé kọ̀rọ̀ kan lókè àjà, ju pé kí eniyan máa bá oníjàngbọ̀n obinrin gbé ilé lọ.
Kà ÌWÉ ÒWE 21
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ÌWÉ ÒWE 21:8-9
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò