Owe 16:31-33
Owe 16:31-33 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ade ogo li ori ewú, bi a ba ri i li ọ̀na ododo. Ẹniti o lọra ati binu, o san jù alagbara lọ; ẹniti o si ṣe akoso ẹmi rẹ̀, o jù ẹniti o ṣẹgun ilu lọ. A ṣẹ́ keke dà si iṣẹpo aṣọ; ṣugbọn gbogbo idajọ rẹ̀ lọwọ Oluwa ni.
Pín
Kà Owe 16