Ẹk. Jer 3:31-33
Ẹk. Jer 3:31-33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Ènìyàn kò di ìtanù lọ́dọ̀ Olúwa títí láé. Lóòtítọ́ ó mú ìbànújẹ́ wá, yóò fi àánú hàn, nítorí títóbi ni ìfẹ́ rẹ̀. Nítorí kò mọ̀ ọ́n mọ̀ mú ìpọ́njú wá tàbí ìrora wá fún ọmọ ènìyàn.
Pín
Kà Ẹk. Jer 3Ẹk. Jer 3:31-33 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitoriti Oluwa kì yio ṣá ni tì lailai: Bi o tilẹ mu ibanujẹ wá, sibẹ on o ni irọnu gẹgẹ bi ọ̀pọlọpọ ãnu rẹ̀. Nitori on kì ifẹ ipọn-ni-loju lati ọkàn rẹ̀ wá, bẹ̃ni kì ibà ọmọ enia ninu jẹ.
Pín
Kà Ẹk. Jer 3