Isa 43:18
Isa 43:18 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹ máṣe ranti nkan ti iṣaju mọ, ati nkan ti atijọ, ẹ máṣe rò wọn.
Pín
Kà Isa 43Isa 43:18 Yoruba Bible (YCE)
ÓLUWA ní, “Ẹ gbàgbé àwọn ohun àtijọ́, kí ẹ sì mú ọkàn kúrò ninu ohun tí ó ti kọjá.
Pín
Kà Isa 43